Smiley face

"Olorun lo seda orin Fuji" - Adewale Ayuba

Adewale Ayuba, eni ti awon ololufe re tun mo si Mr Johnson naa ti salaye ero okan re nipa bi orin fuji se waye.
Ninu alaye re, onkorin naa se alaye wi pe, Olorun lo da orin ati ohun gbogbo to wa nile aye. Sugbon nipa orin fuji, Sikiru Ayinde Barrister ni Olorun lo.
Afikun iroyin nbo laipe...

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment