Smiley face

Asewo ati alarun opolo ni iyawo mi- Oko Mercy Aigbe lo so beem

Mercy Aigbe ati Lanre Gentry nigba tife n dun

Ogbeni Lanre Gentry to je oko Mercy Aigbe tise apejuwe iyawo re, Mercy Aigbe gege bi eni to ni aarun opolo. 

O ni oun loun ma ba lo gba agbo re lowo baba alagbo eleyii to ma je ki alaafia pada si lara ti awon eniyan si fi wo gege bi eni to dape.

Yato si eleyii, o ni iyawo oun feran isekuse pupo. O ni bawo ni okunrin mii yoo se gba yara tuntun fun iyawo ile sita. O ni orisiirisii iwa palapala lo kun owo Mercy eleyii ti oun ti n fara da tipe ko si nnkan ti oun ko fi te e lorun, sibesibe agbere wo lewu bi aso ni.

Sugon sa, Mercy ti ni iro maanu naa n pa ati wi pe mata naa ti wa nile ejo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment