Smiley face

Awon asewo meji ti pa Adeyinka leyin to je "dodo" tan nipinle Ogun

Okunrin kan ti oruko re n je Adeyinka Olayinka ni awon asewo ti gun nigo pa ni ile itura KS Hotel to wa ni Ifo.
Adeyinka lo se agbesun okan ninu awon omo oninabi yii, igba to di owuro ojo keji, ojo Isegun to koja yii, ni ede aiyede waye laaarin won latari owo ti asewo fe gba.
Nibi ni gobe ti sele, ti okan ninu awon ore asewo naa si dasi ija naa. Nibe naa ni won si ti dawo gun ogbeni Adeyinka nigo labiya. Awon omo olosho meji naa ti wa ni atimole awon olopaa bayii.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment