Smiley face

Awon foto ayeye ojo ibi Gani Adams

Aseyori eda ki i se nipa owo tabi dukia to kojo, bikose ipa ati ilakaka lati mu awujo ati awon eniyan awujo re tesiwaju ju ti tele lo. 
 
Eleyii gan-an ni a le fi se apejuwe Otunba Gani Adams to je olori egbe OPC/OPU fun ipa ribiribi to ko lawujo wa. Eniyan pataki yii pe eni odun metadinlaadota (47)ni ogbon ojo osun kerin odun yii, aimoye awon eniyan ni won si peju-pese lati wa bu ola fun omoluabi ati akikanju eda to tun je ojulowo omo oduduwa. 
 
Adura wa ni wi pe, igba odun, odun kan ni.  
 

Awon foto yii je ti Ogbeni +Segun Akanni, olootu http://thedrumonline.blogspot.com
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment