Smiley face

Awon ogbologbo dokita ni won toju Buhari niluu London- Lai Muhammed

Minisita fun etigbo ati asa nile yii, Alaaji Lai Muhammed ti so fun awon oniroyin wi pe, awon dokita akosemose ni won toju Aare Muhammadu Buhari niluu London. Oro yii lo jeyo nigba ti awon oniroyin n bi nipa ilera Buhari leyin ipade to waye lonii niluu Abuja.

Alaaji Lai ni, ko si lie-lie ninu oro mi. E so fun awon omo Naija wi pe awon dokita ti won ka oju osuwon ni won toju Sai Baba niluu London.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment