Ohun ti Gov Ajimobi n se ninu oko ni yii
Gov ipinle Oyo, Sen Abiola Ajimobi ti feto ogbin tuntun lele ni ipinle Oyo lati mu ounje po si i niluu. Siwaju sii, Gomina ni eto tuntun yii yoo mu awon odo bi egberun marun un di eni ti yoo nise lowo.
Reviewed by Olayemi Oniroyin
on
5/31/2017 07:01:00 am
Rating: 5
0 comments:
Post a Comment