Badoo si n da Ikorodu laamu
Won ni awon onise ibi kan wa ni agbegbe Ikorodu ni ilu Eko, eleyii ti adari egbe okunkun yii nje Badoo. Gbogbo igba ni won pa awon eniyan. Badoo lagbo wi pe o ti tun pa odindi idile mii bayii.
Reviewed by Olayemi Oniroyin
on
6/30/2017 02:55:00 pm
Rating: 5
0 comments:
Post a Comment