Smiley face

#HappyBirthday Oluwaseyi Edun

Oni, 4-6-17, ni ojo ibi Oluwaseyi Edun, oserebirin onitiata ile Naijiria. Oserebirin yii naa ni a ti bere si ni gbo ti awon eniyan so wi pe, oun ni ololufe tuntun Adeniyi Johnson. Sugbon eyikeyi won ko ti fidi aheso oro naa mule.

Ju gbogbore lo, a gbadura ire owo, ayo, idunnu fun Asabi omo olojo ibi oni.

Igba odun, odun kan ni.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment