Smiley face

Hon Desmond Elliott pese moto ofe fun awon akekoo ni Surulere

Hon Desmond Elliott, okan lara omo ile igbimo asofin ipinle Eko ti n soju ekun Surulere ti pese oko bogini nla akero ti yoo ma ko awon omo ileewe lofee.

Yato si moto nla akero, osere tiata to di oloselu naa tu pese ibi idanilekoo ero komputa pelu opolopo komputa fun idanilekoo awon omo ileewe.

Gbogbo eniyan lo ti bere si ni gbe oriyin fun Hon Elliott fun aseyori ise akanse tuntun naa ni agbegbe Surulere to wa nipinle Eko Gomina Ambode.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment