Smiley face

Ijo Alaafin Oba Adeyemi Lamide lekenka

Leyin ti Oba Lamide Adeyemi III ti yide de ni ojo odun itunni awe to waye lojo Sande yii, ni awon onilu re ba so kongo siluu. Baba ko fi para rara pelu bi Alaafin se n yose funjo ti gbogbo re si n balu dogba.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment