Smiley face

Iya ibeji olopaa ti bo omoodo re torotoro pelu obe gbigbona

Arabirin olopaa ti oruko re n je Ugo Okochi to gbe ni ipinle Ebonyi lo ti da obe gbigbona lu omoodo re leyin. Arabirin Okochi to sese bimo ibeji la gbo wi pe o se omoodo re bayii pelu esun wi pe omoodo naa ki gboran boro.

#lobatan Awon mummy ba da sharia fun lati owo ara won.

Ile iwosan ni omo naa wa bayii

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment