Smiley face

Kadara n fe suuru

Bi eda ba n sare ko le ba laye, o wa sare titi o fòmó oko reluwe bi ko baa, sugbon ti akoko ko ba ti to ko ni baa. Nigba ti akoko eda ba de, gbogbo ohun to ba se a ma jo bi ogbon, bakan naa la ma jo bi idan.

Kadara n fe suuru.. #talazofuji #Talazo84

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment