Smiley face

Naijiria ti pada si ese aaro, won ti n kosu lo ta loke okun

No automatic alt text available. 
Ile Naijiria ti bere si ni ko nnkan ogbin lo ta loke okun bayii pelu bi won se bere pelu isu tita si oke okun. Awon onwoye eto oro aje ni eyi dun un gbo seti nitori epo robi ti gbogbo wa gbojule ti n ja wale laarin oja agbaye
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment