Smiley face

Nje okunrin le rorun wo? E wo ohun ti oko se fun iyawo re

Agba amofin, to tun je ajafeto omoniyan, Emeka Ugwuonye, lo se afihan foto yii fun gbogbo aye. O ni obirin naa to oun wa fun iranlowo leyin ti oko re so di idakuda bayii pelu ese ati gidigbo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment