Smiley face

Rere run o: Lojo odun itunnu awe, ogofa (120) lo ku ninu ijamba ina

Awon eniyan bi ogofa ni won ti ba odun lo bayii ninu ijamba ina to waye ni agbegbe Ahmad Sharqia to wa ni Bahawalpur ni orileede Pakistan.

Ijamba yii lo waye nigba ti tanka oko epo kan danu nibi to ti fe lori wo kona.

Epo danu, bee ni ina jo, sugbon lojiji ni tanka epo naa dun gbamu bi ado oloro bombu ti opolopo emi ati dukia si sofo lojuese.

Awon oko ati okada to wa ni agbegbe naa lo jona deeru nigba aimoye awon eniyan si fara pa.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment