Smiley face

Saheed Osupa ti se ifilole African Delight TV

Image may contain: 1 person, closeup
Saheed Osupa
Oba Orin Saheed Osupa ti kede ifilole telifisan re eleyii to pe ni African Delight TV.  TV yii je tori ayekujara eleyii to wa lori itakun agbaye  Youtube. Ninu alaye Akorede baba Sulia, o ni telifisan yii yoo ma se afihan awon orin ode ere oun, awon awo orin ati awon iforowero pelu awon oniroyin. O ro awon ololufe re lati tele e loju opo naa fun akotun awon ohun meremere lati owo oba orin Saheed Osupa.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment