Smiley face

#AsoEbi Mercy Aigbe pelu awon omo re

Awon Yoruba ni boode ko dun, bi igbe niluu n ri. Ayo ati idunnu ti pada si aye Mercy bayii pelu bi osere naa se tun padasi bo n ti n se tele, isafihan awon aso oge lorisirisi.

Osere yii lo ni wahala pelu oko re, Lanre, eni to so di ilu bara ki awon mejeeji to pinya. Ibanuje okan yii je ki Mercy karibonu ni awon akoko kan seyin, sugbon bayii, swaga mama ti pada soke.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment