Smiley face

Baba mi ti pe 90 sugbon e ko le gbagbo -Seyi Law

Seyi Law, okan ninu awon alawada ile Naijiria ti se abewo si baba re niluu Ondo.

O se alaye wi pe, baba oun ti pe eni. Aadorun (90) odun sugbon eniyan ko le gbagbo latari bi ara re se ri bi omo tuntun jojolo.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment