Smiley face

E ko le gba eleyii gbo nipa Olumide Oresegun

Olumide Oresegun, agbaoje, ilumooka, ayaworan, onise-ona, ti se igbejade akotun ise re jade eleyii to ti di apewo bayii.

Fun awon ti ko ba mo Olumide tele, yoo soro lati so fun iru awon eniyan bee wi pe, owo ni won fi ya aworan yii.

Sugbon bo ti ri nu un. Aimoye igba ni CNN agbaye ti gbe iroyin won ka ori omokunrin naa latari awon gbankogbi ise opolo to fakiki to gbe jade.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment