Smiley face

Kate Henshaw: Ojo ibi "orekelewa akinkanju obirin"- Kunle Afolayan

Ojulowo orin ki i se nipa ariwo pipa. Gbogbo eni to joko sori aga ko ni siamaanu.

Ti a ba n so nipa agbaoje oserebirin onise tiata Naijiria, abuku ni yoo je ti oruko Kate Henshaw ko ba si loke.

Bi o tile je wi pe omo Calabar ni, sugbon ede Yoruba enu re dasaka gege bi a ti ri ipa re ninu ETI KETA, fiimu Saidi Balogun. Kunle Afolayan se apejuwe Kate Henshaw gege bi "orekelewa akinkanju obirin."

Aimoye eniyan ni won si ti n so nipa emi irele, iwa tutu bi adaba ati oyaya oserebirin to pe eni odun marunlelogoji (45) lonii, July 19.

A fi asiko yii ki oserebirin naa ku ayo odun tuntun. Igba odun, odun kan ni. #HappyBirthday #EniyanPataki

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment