Smiley face

Omobirin ti won gba lowo iku ti n gbe igbe aye iyanu

Orileede Somalia, nibi ti airi ounje je ti gbe wo won lewu, ni awon toko-taya kan ti gbe ri omobirin naa. Won gbe lo si ilu Amerika. Leyin odun di e, eniyan ko le da omobirin naa mo rara. Ile iwe lo wa bayii nibi to ti n ko eko lati di dokita.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment