Smiley face

Omoge asewo ti padanu emi re: Omu ati nnkan omobirin re ni won mu lo

Orekelewa omoge omo ilu Ghana ti gbogbo eniyan mo si DC Queen, lo ti se agbako iku ojiji bayii pelu bo se bo sowo awon odaju eniyan ti won mu awon ibi ikoko ara re lo leyin ti won seku pa a.

Omobirin yii ni won ba oku re ni Dome Kwabenya leyin to gbe oja ale lo sile ijo kan ti n je Just Torch pub.

Nigba ti awon eniyan yoo fi ri oku DC Queen, nnkan omobirin, omu, ati ahon re ti kuro lara re.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment