Smiley face

Were sise lo jawo- Denrele Edun

Denrele Edun, onise amuludun eleyii to gbajumo pelu awon imura kayeefi, ti so wi pe bi aye ko ba ti pe eniyan ni were, a je wi pe eni naa ko ti se ohun ara to le mu tayo.

Se otito ni oro yii?

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment