Smiley face

Won ri omobirin oloju kayefi ni Mile2 niluu Eko

Omo yii ti n ta efo ugwu ninu oja Mile 12 ni ayaworan ti oruko re n je Abimbola Balogun ya foto re wa le. Oruko omo naa a ma je Peace, opolopo awon to ri foto re si so wi eyin-oju re saraoto. Ati wi pe, se ki i se wi pe arun ka lo wa loju omo naa. Kini ero ti yin?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment