Smiley face

Won ti gbe ami-eye Peace Ambassador fun MC Oluomo

Okan ninu awon oloye omo egbe onimoto, Alh Musiliu Akisanya ti gbogbo eniyan mo si MC Oluomo ni won ti fi ami eye Peace Ambassador da lola bayii.

Egbe Lagos State community volunteers ni won gbe ami eye naa fun un nipa akitiyan MC Oluomo lati je ki alaafia joba lawujo wa.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment