Smiley face

Abode Mecca: Ehin goolu Lizzy Anjorin n sana

Oserebirin osere tiata, Lizzy Anjorin ti seripada wale lati ilu Saudi Arabia nibi to ti lo se Hajji odun 2017.
Liz salaye wi pe, gbogbo awon ololufe oun ni oun se adura fun nigba ti oun wa nile mimo.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment