Gege bi iroyin to te wa lowo se n salaye, baalu ijagun awon omo ologun Naijiria ti bere si ni rababa lori ile akogun iko omo ogun Biafra, Nnamdi Kanu to wa ni Umahia ni ipinle Abia. Kanu Nnamdi yii ni won ti fi ofin gbe tipamo sinu ile re wi pe ko gbodo jade.
0 comments:
Post a Comment