Smiley face

E gbadura fun Olanrewaju Adepoju: Awon dokita n reti oba akewi ni orileede India

Ewi Legend, Lanrewaju Adepoju, ready for India medical treatment after donations.
Olanrewaju Adepoju
Agbaọjẹ akewi ile Yoruba, Olanrewaju Adepoju, ti n mura bayii lati gbera lo si ilu India fun itoju oju re ti n yọ ọ lenu. 

Saaju asiko yii ni Baasoro ile Yoruba, Otunba Kola Olootu kede ipe fun iranlowo fun akewi yii eleyii ti awon eniyan oninudidun ọlọrẹ si dide fun iranwo nipa owo. 

Nibayii, Olarewaju Adepoju ko ni pe gbera lo si ilu India nibi won yoo ti se isẹ abẹ fun un ti oju re yoo fi pada bọ sipo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment