Smiley face

Ija ti pari laarin emi ati Yinka Ayefele- Osan onilu

Leyin ikunsinu ati wahala aimoye odun laarin Seye Osan to je okan pataki lara awon onilu Yinka Ayefele, ni ija naa ti pari bayii.

Seye Osan lo kede eleyii, o ni "ija ti tan, ogun si ti dopin laarin emi ati oga mi, Olayinka Joel Ayefele."

A ki won ku oriire igba otun to de ba won. Ire o!

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment