Smiley face

Kayeefi! Won ti bere odun awon oku niluu Indonesia

Odun awon oku je odun kan pataki ti awon eya Torajan ti won wa ni Guusu Sulawesi ni orileede Indonesia maa n se.
Odun yii je odun kan pataki ti tewe tagba maa foju sona si nitori o je odun alarinrin.

Ohun ti awon eniyan maa se ni wi pe, ti odun ba ti de, won yoo wu awon oku eniyan won to ti ku jade.
Won yoo woso si i lorun, pelu orisirisi eso, awon kan tile tun le fi siga ha a  lenu.
Won yoo wa maa safihan re kaakiri adugbo.
Awon ka tun salaye wi pe, asa won yii ki i se odun lasan, a tun le pe ni etutu eleyii to gbajumo ni agbegbe naa.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment