Smiley face

Ohun ti yoo sele ti Buhari ba pa Nnamdi Kanu adari Biafra: Omo Yibo ti salaye

Image result for nnamdi kanu
Nnamdi kanu
Okan lara omo ile Yibo ti oruko re n je Onye Nkuzi‏ ti salaye wi pe, bi ijoba apapo ba fi le gbiyanju lati seku adari iko ti n pe fun idasile Biafra, Nnmdi Kanu, mewaa iru okunrin naa ni yoo pada tun dide lati tesiwaju. Wahala ikehin yoo si gbona jainjain ju ti isaaju lo. Ninu alaye re lo ti n ro ijoba Buhari lati te e jeje.


Alaye ranpe nipa Nnamdi Kanu lati inu Wikipedia

Nwannekaenyi "Nnamdi" Kenny Okwu Kanu (born September 1967) is a British-Nigerianpolitical activist. He is a leading member of one of several Biafran separatist organizations[4], the Indigenous People of Biafra (IPOB), and the director of a London-based radio station Radio Biafra. Kanu was arrested on treason charges in Lagos on 14 October, 2015 and was detained in a Nigerian jail without trial for more than a year-and-a-half, despite various court orders that ruled for his release. When in court, Kanu appeared regularly wearing a Jewish prayer shawl and head covering. He said in court that he "believes in Judaism" and considers himself a Jew. On 28 April 2017 Kanu was released from prison on bail
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment