Smiley face

Wahala obi lori omo: Kini a le fi se apejuwe baba yii?

Omobrin ti iruko re n je Sino, onise ona ayaworan, lati ilu South Africa ti se alaye bi baba re se fi gbogbo aye re sin awon omo to tobi saaju ko to pada si ileewe.

Omibirin yii ni i ki baba re ku oriire leyin to kawe gboye akoko ni eni odun merinlelaadota 54.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment