Smiley face

Olufemi Davies pe eni aadota odun laye

Bi won ba ni ki n pe olorin wa.
Olayemi oba, mo mojulowo olorin to gbamuse.

Oro awada ko, ojogbon to mo'Fa bi Wande omo Abimbola ò pe meji.

Oluwole Soyinka loba ninu ka kowe.
Sorosoro ti o ba Kola Olootu tayo olopon yoo mura gidi.
Femi Davies loga ninu ise iroyin to fakiki.
Iba Gbobaniyi ti won bo bi oke.

Femidavies@50 #HappyBirthday Igba odun, odun kan ni.

Olufemi Davies Metronews Metronews Nigeria

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment