Smiley face

Àwọn ènìyàn ta padà nígbà tá ń gòkè, le pada wúlò ta bá ń sòkalẹ̀ bọ̀

Má gbegbe awon olóore rẹ nígbà tó kéré. Ma seranti awon eniyan ti won  dúró tì ọ nígbà tí kò sì ohunkóhun lọ́wọ́ rẹ nígbà to ba gòkè. Awon Yorùbá bọ, wòn ni ti ore ba ti pẹ,  asiwere ènìyàn a sì má gbàgbé.

Lopo igba, awon eniyan taa pàdé nígbà tán gòkè lè wúlò ta bá ń sòkalè bọ. Sebi atori laye, ènìyàn tó mọ tomorrow kan kò sì. Kosi ẹ̀dá to mọ ọjọ́ ọ̀la.

ma gbàgbé ohun kékeré yìí, nítorí ilé ayé kò too pọn, òfo lórí òfo ni. Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ gbogbo yín pátá. E ṣeun.

E ku ipalemọ ọdún. Odù  ayo ni fún gbogbo wa.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment