Smiley face

Àwọn ọlọ́pàá tí mú ọmọ tí ń fi ogun abenugongo yọ foonu mọ àwọn ènìyàn lára

Àwọn olopaa ti mú ole ti n yo fóònù mo awon ènìyàn lára niluu Eko. Kódà, wọn kan ogun mọ ọ lọ́wọ́.

Bí Ọlọ́run a ṣe má mú yín nìyẹn. Àwọn ọmọ àlè jatijati. Bi ọkan ninu ṣe yọ foonu mo mi lára ni yen lọ́jọ́ ti mo lo ya ise kan ni agbegbe Ketu.

Ó dun mi baje.! Lol 😂

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment