Smiley face

Buhari@75:Ti won ba gbe ère Abdulsalam Abubakar kò ti poju fún ipa to ko lórí oro Nàìjíríà

Aare ológun ìgbà kan, Abdulsalam Abubakar, naa se abewo si Aare Muhammadu Buhari niluu Abuja.

Ṣùgbọ́n ká má paro, Abdulsalam je okan lara awon ènìyàn àpọ́nlé to ye ka má dupe fun nígbà gbogbo. Ó ṣe ìlérí láti dá ìjọba padà fún alagbada, ó sì se bo ti wí. Ó ní agbára láti dá oro ru, sugbon kò se bẹẹ.

#Buhari@75

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment