Smiley face

Muka Ray Eyiwumi sì ilé itura siluu Ikorodu

Agbaoje onise tiata, Ogbeni Muka Ray tí sì ilé itura kan si agbegbe Agura-Gberigbe to wa ni ilu Ikorodu lojo Isegun to koja yii. Aimoye awon ènìyàn lagbo osere ati olorin ni won peju láti bá yọ ayo Ire tuntun naa.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment