Smiley face

"Iro ni won pa mọ mi o, mi ò setan lati gbe àpótí idibo ààrẹ"- Fela Durotoye lọ sọ bẹẹ

Gbajugbaja, olukoni gbogbogbòò , onimo pàtàkì nípa ìṣàkóso àti ọ̀rọ̀ ìṣípayá, Ogbeni Fela Durotoye tí kede wí pé òun kò mọ nípa fọ́tò òun ti won gbe kiri ayelujara lati gbe igba ìbò ààrẹ .

Gégé àlàyé ọkùnrin náà, ó ní bi o tile jẹ wí pé inú òun dùn gẹ́gẹ́ bi àwọn eniyan se fi ife han nipa ìpolongo tí ń lọ, ó ni ṣùgbọ́n sibẹsibẹ eleyii kìí se aba tàbí ero ohun rárá.

Ninu àpilẹ̀kọ tó fi sórí ayelujara, o ni kilokilo ni èyí je fún àwọn aṣáájú wá láti fi àyè sile fún àwọn ọ̀dọ́ láti di ipo isejoba mú. Bakan naa lo ro awon ènìyàn láti ni káàdì ìdìbò lówo nítorí ona kan ṣoṣo ni yii lati yan ẹni tí wọ́n bá fẹ́.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment