Smiley face

Ọwọ́ mẹ́wàá ni Ooni Ojaja kó fún Dangote àti Otedola

Èniyàn lè bá ọba lọ́wọ́ laye òde òní, kosi babara nibẹ. Níwòn ìgbà tí ẹni náà bá jẹ olówó tàbí ènìyàn pàtàkì láwùjọ. Mekunnu ni ko gbọ́dọ̀ dá irú rẹ lasa. Ti mekunnu bá ṣe irú rẹ, oyaju tàbí itapa sì iṣẹṣe ni i jọ lójú ayé. Olówó s'oun gbogbo tán.

Koda, Arole Oodua tiro ara sókè díẹ̀ láti kí Ali kò Dangote àti Femi Otedola nibi ayeye Christmas Carol eléyìí tí Ovation gbé kalẹ .

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment