Smiley face

Séríkí Amuludun of Yorubaland: Oga Bello ni won gbe fun

Wọn ti fi Alhaji Adébáyò Salami tí gbogbo ènìyàn mo sì Oga Bello jẹ Sariki Amuludun of Yorubaland. Àwọn ẹgbẹ́ kan tí ń jẹ Ilorin Emerate Decedents Progressive Union ni wó  we láwàní òye náà lè lórí.

Oga Bello to je bàbá Jelili oniso ni ọ̀pọ̀ àwọn ènìyàn gba gẹ́gẹ́ bí ọkàn pàtàkì tí a ba n so nipa ipilẹ ere tíátà ilé Nàìjíríà olominira.

Oga Bello je musulumi òdodo tó yanranti. Iwa ọmọlúwàbí rẹ ò sì lẹ́lẹ́gbẹ́

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment