Smiley face

Seun Egbegbe ti ká ABD débi GBi! O loun tí gba fun kadara (3)

Bí ó tilè jé wí pé ọ̀pọ̀ awon ọrẹ Seun Egbegbe ni won ti gbàgbé rẹ sì ọgbà ẹ̀wọ̀n, gẹgẹ ohun tá a gbọ́.

Pelu irú ìwà ìtìjú to wú, kosi eni to wù láti ba ole, jaguda, gbewiri, alonilowogba, àti oníjìbìtì bí sún Egbegbe ṣe.

Enikan tí ń yọjú sì ni gbogbo igba ni orebirin rẹ tí ń jẹ Olanike Yusuf ẹni tó bimo obìnrin fún Seun Egbegbe nínú osu karun-un odun 2017.

Inu ogba ẹ̀wọ̀n to wa ni Ikoyi náà ni Seun Egbegbe ti fi orúkọ ọmọ náà ranse.

Ṣùgbọ́n sa, won ni kọ́ni buruburu ko ma ku enikan moni, ènìyàn tí yóò kú là ó mọ.

Okan nínú àwọn olólùfẹ́ Seun Egbegbe bẹ̀ẹ́wò nínú ọgbà ẹ̀wọ̀n to wa nIkoyi.

Ọkùnrin to kan si Seun ṣùgbọ́n tí kò fẹ́ kí n dárúko oun ṣàlàyé ohun tí ojú rẹ rí àti ipò tí Seun Egbegbe wa.

Ẹ yẹ àtẹ yìí wo fún abala kẹrin (4) iroyin yii.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment