Smiley face

OJULOWO ỌMỌ YORÙBÁ: Ẹ pàdé Isaac Owolabi pelu Morenike

"Ẹ kú u dééde àsìkò yìí o, A sì kú iṣẹ́ àtàárọ̀, Àlejò mi àkọ́kọ́ lórí OJULOWO ỌMỌ YORÙBÁ ti yóò wayé lọjọ Àbámẹ́ta lori àtẹ Yoruba Dun ní déédé agogo mẹ́rin irọ̀lẹ́ ni Ọ̀gbẹ́ni Isaac Owolabi (Isaaco Media)... Ẹ kú ojú lọ́nà o!"

Olukede: Yeye Agbasaga Morenike Toriola

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

1 comments: