Smiley face

Ọmọkùnrin tí ń jisu onisu wá tí ha sínú kòtò ọrun báyìí

Ọmọkùnrin tí ń jisu onisu wá lo tí ha sínú kòtò ọrun báyìí ni ìlú Mabel to wá lorile-ede Uganda.

Ọmọkùnrin to fi ìyàwó ati awon omo sílè ni wọn ni kii se ìgbà àkókò ni yii ti yoo ma gbé àlè, eléyìí tí òun náà jẹ ìyáwo ilé, wa si ile Ìtura kan tí ń je Triple Zero Guesthouse.

Ṣùgbọ́n èyí tí wọn ṣe gbeyin yìí ló mú wọn gba penalty lọ throwing. Ń ṣe ní àwon  méjèèjì lè papọ níbi wọn tí ń lalakukulala ara won.

Gbogbo igbiyanju àwọn oníṣègùn ibile ìlú náà láti tú wọn silẹ lọ tí ja si pàbó báyìí .

Àwọn kan ni oseese kò jẹ ọkọ ọmọbìnrin náà lo dẹ pakute silẹ fún wọn. Àti wí pé, òun ni yóò mọ àṣírí kọ́kọ́rọ́ tí yóò tún won silẹ

E wo foto yoku níbi www.olayemioniroyinblog.com

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment