Smiley face

Yeye Agbasaga Morenike Toriola: OJÚLÓWÓ ỌMỌ YORÙBÁ

Ẹ kú asiko yii ẹyin ènìyàn wá, eleyii ni lati fi tó yín létí wí pé, abala eto tuntun yóò gorí atẹ Yorùbá Dùn eléyìí tí a n pè ní OJÚLÓWÓ ỌMỌ YORÙBÁ

Níbi ni a ti má ṣe ifọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò fún àwon ọmọ Yorùbá tàbí àwọn olólùfẹ́ Yorùbá láti mo nípa wọn, òye àti imo wọn nípa èdè, àṣà ati ìṣe Yoruba àti àwọn nǹkan mììràn tó lè mu Yoruba ati àwùjọ wá tesiwaju. Ẹnikẹ́ni ló ni anfaani lati jẹ́ àlejò lórí Ojúlówó Ọmọ Yorùbá, gbogbo wa bákan náà lásì ni anfaani lati béèrè ìbéèrè tá bá fẹ́ lọ́wọ́ àlejò wa nígbà tí èmi ọmọ yín, àbúrò yín Yeye Agbasaga Morenike Toriola yóò má ṣe atọ́kùn eto naa. Inú mi yóò dùn láti mọ èróngbà tàbí amọran yín lórí eto yìí.

Ẹ ṣeun

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment