Smiley face

Ẹbí Olórin: Killington Ayinla pẹ̀lú Sheriff ọmọ rẹ

Àwọn Yoruba ni, tokete bá dàgbà, ọmú ọmọ rẹ ni i mú. Omo Killington Ayinla, Sheriff, ẹni tí àwọn ènìyàn mo sì Big Sheff tí òun náà jẹ olórin takasufe lọ tí bẹ̀rẹ̀ si ni polongo wí pé, àwo tuntun bàbà òun kò ni pé jáde. Eléyìí lo ṣe lórí ẹ̀rọ ayélujára nígbà tó ńṣe àfihàn àwòrán ara rẹ pẹlu Alhaji Kebe.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment