Smiley face

Ẹ̀jẹ̀ san ni Zamfara: 41 ènìyàn tí wọlẹ̀ sún lójú bajinatu àwọn odaju ẹ̀dá

Ni Ipinle Zamfara, n se ni wọn tẹ òkú àwọn ènìyàn sílè bí ìgbà tí wọn ba le ìṣù sílè loja oritamerin Ibadan. Bi ènìyàn bá dé ijoba ibile Birani Zurmi, bí ẹni náà bá jẹ ori ahun, bó bá fojú kan bí àwọn onise ibi omo agbegbon ṣe pa àwọn ènìyàn ní ìpakúpa yóò wà omi ẹkùn mu bí gaari. Àwọn ènìyàn tí wọn kò dín ni mọkọnlelogoji ni wọn ti sìn báyìí ni Ipinle naa leyin ikolu àwọn ìka ènìyàn kan tí wọn ṣàdédé yawo agbegbe naa .

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment