Smiley face

K1, Malaika, ní won tí ranse ibanikedun sì Olamide Baddo ọmọ òrukàn

Àìmọye àwọn ènìyàn ní wón ti ń ranse ibanikedun sì Olamide Baddo pelu bo se pàdánù ìyá rẹ logbon ojo oṣù kinni odun 2018. Ọjọ yìí kan náà ni Ọmọ Science Student ń yọ ayọ̀ ọjọ́ ìbí ọmọ rẹ kì ikú to mú ìyà tó bí òun gan-an lọmọ lọ.

Ọlọ́run yóò dúró tì ìdílé Adedeji. Àmìn 

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment