Smiley face

"Osu Keje ọdún ló yẹ kí n bímọ ṣùgbọ́n oṣù kẹrin lọ wà saye" - Ìyá Iyanu

"Ona ara jí Ọlọ́run gbà jomiloju. Mo bí ọmọ nínú oṣù kẹrin ọdún 2017 ṣùgbọ́n oṣù keje gan-an ló yẹ kó wáyé. Ọkàn mi kò sókè, ó sì dabi ẹni wí pé Ire na kò ní tọjọ. Ṣùgbọ́n sì ìyàlẹ́nu mi, ọmọ kò gbẹjẹ, kò gbà afẹ́fẹ́ oxygen, koko lara rẹ le. Títí di àkókò yii, àlàáfíà ni ọmọ mi wá. Ẹ rí wí pé ìyanu ní Ọlọ́run fún mi bi" - Ìyá Ìyanu 

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment