Smiley face

Ohun tí ẹ kò mọ nípa Shina Rambo ògbólógbòó ọlọ́ṣà (3)

Gẹ́gẹ́ bí ìwádìí tí ṣe, Shina Rambo, ògbólógbòó ọlọ́ṣà tí fi moto feyin sáré rí (rifaasi) láti Ìbàdàn de ilu ẹ̀kọ́.

Gẹ́gẹ́ bí a ṣe gbọ, Shina Rambo ni ìyàwó ọrun kan eléyìí to ma ń wá jáde to bá ti fẹ́ lọ jalè. Ẹnikẹ́ni kì í rí ojú obìnrin yìí nítorí wí pé a má daso bójú bí elehaa ni.

Àwọn kan tilẹ̀ sọ wí pé èmi àìrí ni obirin náà àti wí pé kì í ṣe ènìyàn ẹlẹ́ran ara.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment