Smiley face

Olajumoke ọmọ oniburedi sì ń migboro titi

Olajumoke Orisaguna tí gbogbo ènìyàn mo sì Olajumoke ọmọ oniburedi sì ń jẹun lọ nígboro pelu àwọn ipolowo orisirisi eléyìí to ń ṣe fún àwọn onise oge. Ọkàn nínú àwọn ìṣe rẹ ni yìí tó ṣe fún ileese aranso kán  tí ń ranso ìyàwó lorisirisi.


Fún ipolowo àti ikede
+2348032394964
yemoford@gmail.com

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment